Romans 8:1

Ìyè nípasẹ̀ ẹ̀mí

1 aNítorí náà, kò sí ìdálẹ́bi nísinsin yìí fún àwọn tí ó wà nínú Kristi Jesu, àwọn tí kò rìn nípa ti ara, bí kò ṣe nípa ti Ẹ̀mí.
Copyright information for YorBMYO